Àwọn Nọ́mbà Yorùbá
0 odo
1 ení
2 èjì
3 ẹ̀ta
4 ẹ̀rin
5 àrún
6 ẹ̀fà
7 èje
8 ẹ̀jọ
9 ẹ̀sán
10 ẹ̀wá
11 ọ̀kanlá
12 èjìlá
13 ẹ̀talá
14 ẹ̀rinlá
15 ẹ́ẹdógún
16 ẹẹ́rìndílógún
17 eétàdílógún
18 eéjìdílógún
19 oókàndílógún
20 ogún
21 ọkanlelogun
22 ejilelogun
23 ẹtalelogun
24 ẹrinlelogun
25 ẹ́ẹdọ́gbọ̀n
26 ẹrindinlọgbọn
27 ẹtadinlọgbọn
28 ejidinlọgbọn
29 ọkandinlọgbọn
30 ọgbọ̀n
31 ọkanlelọgbọn
32 ejilelọgbọn
33 ẹtalelọgbọn
34 ẹrinlelọgbọn
35 arundinlogoji
36 ẹrindinlogoji
37 ẹtadinlogoji
38 ejidinlogoji
39 ọkandinlogoji
40 ogójì
50 àádọ́ta
60 ọgọ́ta
70 àádọ́rin
80 ọgọ́rin
90 àádọ́rùn
100 ọgọ́rùn
110 àádọ́fà
120 ọgọ́fà
130 àádóje
140 ogóje
150 àádọ́jọ
160 ọgọ́jọ
170 àádọ́sán
180 ọgọ́sàn
190 ẹ̀wadilúɡba
200 igba
300 ọ̀ọ́dúrún
400 irinwó
500 ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀ta
600 ẹgbẹ̀ta
700 ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀rin
800 ẹgbẹ̀rin
900 ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún
1,000 ẹgbẹ̀rún
2,000 ẹgbẹ̀wá
3,000 ẹgbẹ́ẹdógún
4,000 ẹgbàajì
5,000 ẹgbẹ́ẹdọ́gbọ̀n
6,000 ẹgbàáta
7,000 ẹ̀ẹ́dẹ́ɡbarin
8,000 ẹgbàárin
9,000 ẹ̀ẹ́dẹ́ɡbàárùn
10,000 ẹgbàárùn
100,000 ọkẹ́ marun
1,000,000 àádọ́ta ọkẹ́ Adeola Ready (talk) 12:27, 25 September 2021 (UTC)Reply[reply]